Sáàmù 68:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ọlọ́run tòótọ́ ni Ọlọ́run tó ń gbà wá là;+Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sì ń gbani lọ́wọ́ ikú.+