Sáàmù 22:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Àmọ́ kòkòrò mùkúlú ni mí, èmi kì í ṣe èèyàn,Àwọn èèyàn ń fi mí ṣẹ̀sín,* aráyé ò sì kà mí sí.+