Sáàmù 31:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Gbogbo àwọn ọ̀tá mi ń fi mí ṣẹ̀sín,+Pàápàá àwọn aládùúgbò mi. Mo ti di ẹni àríbẹ̀rù lójú àwọn ojúlùmọ̀ mi;Tí wọ́n bá rí mi lóde, ṣe ni wọ́n ń sá fún mi.+ Àìsáyà 53:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Àwọn èèyàn kórìíra rẹ̀, wọ́n sì yẹra fún un,+Ọkùnrin tó mọ bí ìrora ṣe ń rí,* tó sì mọ àìsàn dunjú. Ó dà bí ẹni pé ojú rẹ̀ pa mọ́ fún wa.* Wọ́n kórìíra rẹ̀, a sì kà á sí ẹni tí kò já mọ́ nǹkan kan.+
11 Gbogbo àwọn ọ̀tá mi ń fi mí ṣẹ̀sín,+Pàápàá àwọn aládùúgbò mi. Mo ti di ẹni àríbẹ̀rù lójú àwọn ojúlùmọ̀ mi;Tí wọ́n bá rí mi lóde, ṣe ni wọ́n ń sá fún mi.+
3 Àwọn èèyàn kórìíra rẹ̀, wọ́n sì yẹra fún un,+Ọkùnrin tó mọ bí ìrora ṣe ń rí,* tó sì mọ àìsàn dunjú. Ó dà bí ẹni pé ojú rẹ̀ pa mọ́ fún wa.* Wọ́n kórìíra rẹ̀, a sì kà á sí ẹni tí kò já mọ́ nǹkan kan.+