Sáàmù 22:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Gbogbo àwọn tó ń rí mi ló ń fi mí ṣe yẹ̀yẹ́;+Wọ́n ń yínmú, wọ́n sì ń mi orí wọn, pé:+ Mátíù 26:67, 68 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 67 Wọ́n wá tutọ́ sí i lójú,+ wọ́n sì gbá a ní ẹ̀ṣẹ́.+ Àwọn míì gbá a lójú,+ 68 wọ́n ní: “Sọ tẹ́lẹ̀ fún wa, ìwọ Kristi. Ta ló gbá ọ?” Jòhánù 6:66 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 66 Nítorí èyí, ọ̀pọ̀ lára àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ pa dà sídìí àwọn nǹkan tí wọ́n ti fi sílẹ̀,+ wọn ò sì bá a rìn mọ́. 1 Pétérù 2:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Bí ẹ ṣe wá sọ́dọ̀ rẹ̀, ẹni tó jẹ́ òkúta ààyè tí àwọn èèyàn kọ̀ sílẹ̀,+ àmọ́ tó jẹ́ àyànfẹ́, tó sì ṣeyebíye lójú Ọlọ́run,+
67 Wọ́n wá tutọ́ sí i lójú,+ wọ́n sì gbá a ní ẹ̀ṣẹ́.+ Àwọn míì gbá a lójú,+ 68 wọ́n ní: “Sọ tẹ́lẹ̀ fún wa, ìwọ Kristi. Ta ló gbá ọ?”
66 Nítorí èyí, ọ̀pọ̀ lára àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ pa dà sídìí àwọn nǹkan tí wọ́n ti fi sílẹ̀,+ wọn ò sì bá a rìn mọ́.
4 Bí ẹ ṣe wá sọ́dọ̀ rẹ̀, ẹni tó jẹ́ òkúta ààyè tí àwọn èèyàn kọ̀ sílẹ̀,+ àmọ́ tó jẹ́ àyànfẹ́, tó sì ṣeyebíye lójú Ọlọ́run,+