ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 27:48
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 48 Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, ọ̀kan lára wọn sáré lọ mú kànrìnkàn, ó sì rẹ ẹ́ sínú wáìnì kíkan, ó wá fi sórí ọ̀pá esùsú, ó sì fún un pé kó mu ún.+

  • Máàkù 15:36
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 36 Ẹnì kan wá sáré lọ rẹ kànrìnkàn sínú wáìnì kíkan, ó fi sórí ọ̀pá esùsú, ó sì fún un pé kó mu ún,+ ó ní: “Ẹ fi sílẹ̀! Ká wò ó bóyá Èlíjà máa wá gbé e sọ̀ kalẹ̀.”

  • Lúùkù 23:36
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 36 Àwọn ọmọ ogun pàápàá fi ṣe yẹ̀yẹ́, wọ́n wá, wọ́n sì fún un ní wáìnì kíkan,+

  • Jòhánù 19:29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 Ìṣà kan wà níbẹ̀ tí wáìnì kíkan kún inú rẹ̀. Torí náà, wọ́n fi kànrìnkàn tí wọ́n rẹ sínú wáìnì kíkan sórí pòròpórò hísópù,* wọ́n sì gbé e sí i lẹ́nu.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́