Sáàmù 69:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Májèlé* ni wọ́n fún mi dípò oúnjẹ,+Ọtí kíkan ni wọ́n sì fún mi láti fi pa òùngbẹ.+ Jòhánù 19:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Ìṣà kan wà níbẹ̀ tí wáìnì kíkan kún inú rẹ̀. Torí náà, wọ́n fi kànrìnkàn tí wọ́n rẹ sínú wáìnì kíkan sórí pòròpórò hísópù,* wọ́n sì gbé e sí i lẹ́nu.+
29 Ìṣà kan wà níbẹ̀ tí wáìnì kíkan kún inú rẹ̀. Torí náà, wọ́n fi kànrìnkàn tí wọ́n rẹ sínú wáìnì kíkan sórí pòròpórò hísópù,* wọ́n sì gbé e sí i lẹ́nu.+