-
Sáàmù 21:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Wàá ṣe wọ́n bí ohun tí a jù sínú iná ìléru ní àkókò tí o yàn láti fiyè sí wọn.
Jèhófà máa gbé wọn mì nínú ìbínú rẹ̀, iná á sì jó wọn run.+
-