3 Bẹ́ẹ̀ ni, mo fẹ́ kí ìwọ náà, gẹ́gẹ́ bí alábàáṣiṣẹ́ tòótọ́,* máa ṣèrànwọ́ fún àwọn obìnrin yìí, wọ́n ti sapá* pẹ̀lú mi nítorí ìhìn rere, pẹ̀lú Kílẹ́mẹ́ǹtì àti àwọn yòókù tí a jọ ń ṣiṣẹ́, àwọn tí orúkọ wọn wà nínú ìwé ìyè.+
5 Torí náà, ẹni tó bá ṣẹ́gun+ máa wọ aṣọ funfun,+ mi ò ní yọ orúkọ rẹ̀ kúrò* nínú ìwé ìyè,+ màá sì fi hàn pé mo mọ orúkọ rẹ̀ níwájú Baba mi àti níwájú àwọn áńgẹ́lì rẹ̀.+