Ìfihàn 4:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ìtẹ́ mẹ́rìnlélógún (24) wà yí ká ìtẹ́ náà, mo rí àwọn àgbààgbà mẹ́rìnlélógún (24)+ tí wọ́n wọ aṣọ funfun, wọ́n jókòó sórí àwọn ìtẹ́ náà, wọ́n sì dé adé wúrà. Ìfihàn 19:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Àní, a ti jẹ́ kó wọ aṣọ ọ̀gbọ̀ tó dáa,* tó ń tàn yòò, tó sì mọ́ tónítóní, aṣọ ọ̀gbọ̀ tó dáa náà dúró fún àwọn iṣẹ́ òdodo àwọn ẹni mímọ́.”+
4 Ìtẹ́ mẹ́rìnlélógún (24) wà yí ká ìtẹ́ náà, mo rí àwọn àgbààgbà mẹ́rìnlélógún (24)+ tí wọ́n wọ aṣọ funfun, wọ́n jókòó sórí àwọn ìtẹ́ náà, wọ́n sì dé adé wúrà.
8 Àní, a ti jẹ́ kó wọ aṣọ ọ̀gbọ̀ tó dáa,* tó ń tàn yòò, tó sì mọ́ tónítóní, aṣọ ọ̀gbọ̀ tó dáa náà dúró fún àwọn iṣẹ́ òdodo àwọn ẹni mímọ́.”+