Àìsáyà 61:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Wọ́n máa mọ àwọn ọmọ* wọn láàárín àwọn orílẹ̀-èdè +Àti àtọmọdọ́mọ wọn láàárín àwọn èèyàn. Gbogbo àwọn tó bá rí wọn máa dá wọn mọ̀,Pé àwọn ni ọmọ* tí Jèhófà bù kún.”+ Àìsáyà 66:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 “Bí ọ̀run tuntun àti ayé tuntun+ tí mò ń dá ṣe máa dúró níwájú mi,” ni Jèhófà wí, “bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọmọ* yín àti orúkọ yín ṣe máa dúró.”+
9 Wọ́n máa mọ àwọn ọmọ* wọn láàárín àwọn orílẹ̀-èdè +Àti àtọmọdọ́mọ wọn láàárín àwọn èèyàn. Gbogbo àwọn tó bá rí wọn máa dá wọn mọ̀,Pé àwọn ni ọmọ* tí Jèhófà bù kún.”+
22 “Bí ọ̀run tuntun àti ayé tuntun+ tí mò ń dá ṣe máa dúró níwájú mi,” ni Jèhófà wí, “bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọmọ* yín àti orúkọ yín ṣe máa dúró.”+