Sáàmù 22:9, 10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ìwọ ni Ó gbé mi jáde láti inú ìyá mi,+Ìwọ ni O mú kí ọkàn mi balẹ̀ ní àyà ìyá mi. 10 Ọwọ́ rẹ ni mo wà* látìgbà tí wọ́n ti bí mi;Ìwọ ni Ọlọ́run mi láti inú ìyá mi wá. Sáàmù 139:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Kódà, ojú rẹ rí mi nígbà tí mo ṣì wà nínú ikùn;*Gbogbo àwọn ẹ̀yà rẹ̀ wà lákọsílẹ̀ nínú ìwé rẹNí ti àwọn ọjọ́ tí o ṣẹ̀dá wọn,Kí ìkankan lára wọn tó wà. Àìsáyà 46:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 “Fetí sí mi, ìwọ ilé Jékọ́bù àti gbogbo ẹ̀yin tó ṣẹ́ kù ní ilé Ísírẹ́lì,+Ẹ̀yin tí mò ń tì lẹ́yìn látìgbà tí a ti bí yín, tí mo sì gbé látinú oyún.+
9 Ìwọ ni Ó gbé mi jáde láti inú ìyá mi,+Ìwọ ni O mú kí ọkàn mi balẹ̀ ní àyà ìyá mi. 10 Ọwọ́ rẹ ni mo wà* látìgbà tí wọ́n ti bí mi;Ìwọ ni Ọlọ́run mi láti inú ìyá mi wá.
16 Kódà, ojú rẹ rí mi nígbà tí mo ṣì wà nínú ikùn;*Gbogbo àwọn ẹ̀yà rẹ̀ wà lákọsílẹ̀ nínú ìwé rẹNí ti àwọn ọjọ́ tí o ṣẹ̀dá wọn,Kí ìkankan lára wọn tó wà.
3 “Fetí sí mi, ìwọ ilé Jékọ́bù àti gbogbo ẹ̀yin tó ṣẹ́ kù ní ilé Ísírẹ́lì,+Ẹ̀yin tí mò ń tì lẹ́yìn látìgbà tí a ti bí yín, tí mo sì gbé látinú oyún.+