Sáàmù 92:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Kódà nígbà arúgbó* wọn, wọ́n á máa lókun;+Wọ́n á ṣì máa ta kébé,* ara wọn á sì máa dán,+