ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 71:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Kódà tí mo bá darúgbó, tí mo sì hu ewú, Ọlọ́run, má fi mí sílẹ̀.+

      Jẹ́ kí n lè sọ nípa agbára* rẹ fún ìran tó ń bọ̀,

      Kí n sì sọ nípa agbára ńlá rẹ fún gbogbo àwọn tó ń bọ̀.+

  • Òwe 16:31
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 31 Ewú orí jẹ́ adé ẹwà*+

      Nígbà tí a bá rí i ní ọ̀nà òdodo.+

  • Àìsáyà 40:31
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 31 Àmọ́ àwọn tó gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà máa jèrè okun pa dà.

      Wọ́n máa fi ìyẹ́ fò lọ sókè réré bí ẹyẹ idì.+

      Wọ́n máa sáré, okun ò ní tán nínú wọn;

      Wọ́n máa rìn, kò sì ní rẹ̀ wọ́n.”+

  • Àìsáyà 46:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  4 Títí o fi máa dàgbà, mi ò ní yí pa dà;+

      Títí irun rẹ fi máa funfun, mi ò ní yéé gbé ọ.

      Bí mo ti ń ṣe, màá gbé ọ, màá rù ọ́, màá sì gbà ọ́ sílẹ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́