Sáàmù 37:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Mo ti jẹ́ ọ̀dọ́ rí, àmọ́ ní báyìí mo ti darúgbó,Síbẹ̀, mi ò tíì rí i kí a pa olódodo tì,+Tàbí kí àwọn ọmọ rẹ̀ máa wá oúnjẹ* kiri.+ Sáàmù 71:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Má ṣe gbé mi sọ nù ní ọjọ́ ogbó mi;+Má pa mí tì nígbà tí mi ò bá lágbára mọ́.+
25 Mo ti jẹ́ ọ̀dọ́ rí, àmọ́ ní báyìí mo ti darúgbó,Síbẹ̀, mi ò tíì rí i kí a pa olódodo tì,+Tàbí kí àwọn ọmọ rẹ̀ máa wá oúnjẹ* kiri.+