Sáàmù 73:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Àárẹ̀ lè mú ara mi àti ọkàn mi,Àmọ́ Ọlọ́run ni àpáta ọkàn mi àti ìpín mi títí láé.+ Oníwàásù 12:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 ní ọjọ́ tí àwọn ẹ̀ṣọ́* ilé ń gbọ̀n pẹ̀pẹ̀,* tí àwọn ọkùnrin alágbára sì tẹ̀, tí àwọn obìnrin tó ń lọ nǹkan dáwọ́ dúró nítorí pé wọn ò pọ̀ mọ́, tí àwọn ọmọge tó ń wo ìta lójú fèrèsé* sì rí i pé òkùnkùn ṣú;+
3 ní ọjọ́ tí àwọn ẹ̀ṣọ́* ilé ń gbọ̀n pẹ̀pẹ̀,* tí àwọn ọkùnrin alágbára sì tẹ̀, tí àwọn obìnrin tó ń lọ nǹkan dáwọ́ dúró nítorí pé wọn ò pọ̀ mọ́, tí àwọn ọmọge tó ń wo ìta lójú fèrèsé* sì rí i pé òkùnkùn ṣú;+