Sáàmù 16:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Jèhófà ni ìpín mi, apá tí ó kàn mí+ àti ife mi.+ O dáàbò bo ogún mi. Ìdárò 3:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Mo* sọ pé, “Jèhófà ni ìpín mi,+ ìdí nìyẹn tí màá ṣe fi sùúrù dúró dè é.”+