Sáàmù 16:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Jèhófà ni ìpín mi, apá tí ó kàn mí+ àti ife mi.+ O dáàbò bo ogún mi. Sáàmù 73:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Àárẹ̀ lè mú ara mi àti ọkàn mi,Àmọ́ Ọlọ́run ni àpáta ọkàn mi àti ìpín mi títí láé.+ Sáàmù 142:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Jèhófà, mo ké pè ọ́ fún ìrànlọ́wọ́. Mo sọ pé: “Ìwọ ni ibi ààbò mi,+Gbogbo ohun tí mo ní* lórí ilẹ̀ alààyè.”
5 Jèhófà, mo ké pè ọ́ fún ìrànlọ́wọ́. Mo sọ pé: “Ìwọ ni ibi ààbò mi,+Gbogbo ohun tí mo ní* lórí ilẹ̀ alààyè.”