Sáàmù 73:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Àárẹ̀ lè mú ara mi àti ọkàn mi,Àmọ́ Ọlọ́run ni àpáta ọkàn mi àti ìpín mi títí láé.+