Sáàmù 3:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ọ̀pọ̀ ń sọ nípa mi* pé: “Ọlọ́run ò ní gbà á sílẹ̀.”+ (Sélà)* Sáàmù 42:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Àwọn ọ̀tá mi ń fi mí ṣẹ̀sín nítorí ìkórìíra tó lágbára tí wọ́n ní sí mi;*Láti àárọ̀ ṣúlẹ̀, wọ́n ń fi mí ṣẹ̀sín, wọ́n ń sọ pé: “Ọlọ́run rẹ dà?”+ Mátíù 27:42, 43 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 42 “Ó gba àwọn ẹlòmíì là; kò lè gba ara rẹ̀ là! Òun ni Ọba Ísírẹ́lì;+ kó sọ̀ kalẹ̀ báyìí látorí òpó igi oró,* a sì máa gbà á gbọ́. 43 Ó ti gbẹ́kẹ̀ lé Ọlọ́run; kí Ó gbà á sílẹ̀ báyìí tí Ó bá fẹ́ ẹ,+ torí ó sọ pé, ‘Ọmọ Ọlọ́run ni mí.’”+
2 Ọ̀pọ̀ ń sọ nípa mi* pé: “Ọlọ́run ò ní gbà á sílẹ̀.”+ (Sélà)* Sáàmù 42:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Àwọn ọ̀tá mi ń fi mí ṣẹ̀sín nítorí ìkórìíra tó lágbára tí wọ́n ní sí mi;*Láti àárọ̀ ṣúlẹ̀, wọ́n ń fi mí ṣẹ̀sín, wọ́n ń sọ pé: “Ọlọ́run rẹ dà?”+ Mátíù 27:42, 43 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 42 “Ó gba àwọn ẹlòmíì là; kò lè gba ara rẹ̀ là! Òun ni Ọba Ísírẹ́lì;+ kó sọ̀ kalẹ̀ báyìí látorí òpó igi oró,* a sì máa gbà á gbọ́. 43 Ó ti gbẹ́kẹ̀ lé Ọlọ́run; kí Ó gbà á sílẹ̀ báyìí tí Ó bá fẹ́ ẹ,+ torí ó sọ pé, ‘Ọmọ Ọlọ́run ni mí.’”+
10 Àwọn ọ̀tá mi ń fi mí ṣẹ̀sín nítorí ìkórìíra tó lágbára tí wọ́n ní sí mi;*Láti àárọ̀ ṣúlẹ̀, wọ́n ń fi mí ṣẹ̀sín, wọ́n ń sọ pé: “Ọlọ́run rẹ dà?”+
42 “Ó gba àwọn ẹlòmíì là; kò lè gba ara rẹ̀ là! Òun ni Ọba Ísírẹ́lì;+ kó sọ̀ kalẹ̀ báyìí látorí òpó igi oró,* a sì máa gbà á gbọ́. 43 Ó ti gbẹ́kẹ̀ lé Ọlọ́run; kí Ó gbà á sílẹ̀ báyìí tí Ó bá fẹ́ ẹ,+ torí ó sọ pé, ‘Ọmọ Ọlọ́run ni mí.’”+