Sáàmù 71:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Nítorí ìwọ ni ìrètí mi, Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ;Ìwọ ni mo gbẹ́kẹ̀ lé* láti ìgbà èwe mi wá.+