Sáàmù 63:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ìpín tó dára jù lọ, tó sì ṣeyebíye jù lọ la fi tẹ́ mi* lọ́rùn,*Torí náà, ẹnu mi yóò yìn ọ́, ètè mi yóò sì kọrin.+ Sáàmù 104:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Màá kọrin sí Jèhófà+ jálẹ̀ ayé mi;Màá kọ orin ìyìn* sí Ọlọ́run mi ní gbogbo ìgbà tí mo bá fi wà láàyè.+
5 Ìpín tó dára jù lọ, tó sì ṣeyebíye jù lọ la fi tẹ́ mi* lọ́rùn,*Torí náà, ẹnu mi yóò yìn ọ́, ètè mi yóò sì kọrin.+
33 Màá kọrin sí Jèhófà+ jálẹ̀ ayé mi;Màá kọ orin ìyìn* sí Ọlọ́run mi ní gbogbo ìgbà tí mo bá fi wà láàyè.+