Sáàmù 71:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ètè mi yóò máa kígbe ayọ̀ bí mo ṣe ń kọ orin ìyìn sí ọ,+Nítorí o gba ẹ̀mí mi là.*+ Sáàmù 135:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ẹ yin Jáà, nítorí Jèhófà jẹ́ ẹni rere.+ Ẹ kọ orin ìyìn* sí orúkọ rẹ̀, nítorí ó dára.