Sáàmù 119:68 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 68 Ẹni rere ni ọ́,+ àwọn iṣẹ́ rẹ sì dára. Kọ́ mi ní àwọn ìlànà rẹ.+ Mátíù 19:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ó sọ fún un pé: “Kí ló dé tí o fi ń bi mí nípa ohun rere? Ẹni rere kan ló wà.+ Àmọ́ o, tí o bá fẹ́ jogún ìyè, máa pa àwọn àṣẹ mọ́ nígbà gbogbo.”+
17 Ó sọ fún un pé: “Kí ló dé tí o fi ń bi mí nípa ohun rere? Ẹni rere kan ló wà.+ Àmọ́ o, tí o bá fẹ́ jogún ìyè, máa pa àwọn àṣẹ mọ́ nígbà gbogbo.”+