Àìsáyà 48:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí, Olùtúnrà rẹ, Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì:+ “Èmi, Jèhófà, ni Ọlọ́run rẹ,Ẹni tó ń kọ́ ọ kí o lè ṣe ara rẹ láǹfààní,*+Ẹni tó ń jẹ́ kí o mọ ọ̀nà tó yẹ kí o máa rìn.+
17 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí, Olùtúnrà rẹ, Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì:+ “Èmi, Jèhófà, ni Ọlọ́run rẹ,Ẹni tó ń kọ́ ọ kí o lè ṣe ara rẹ láǹfààní,*+Ẹni tó ń jẹ́ kí o mọ ọ̀nà tó yẹ kí o máa rìn.+