Àìsáyà 43:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí, Olùtúnrà yín,+ Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì:+ “Nítorí yín, màá ránṣẹ́ sí Bábílónì, màá sì gé gbogbo ọ̀pá ìdábùú ẹnubodè lulẹ̀,+Àwọn ará Kálídíà sì máa ké jáde nínú ìdààmú, nínú àwọn ọkọ̀ òkun wọn.+ Àìsáyà 44:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,Ọba Ísírẹ́lì+ àti Olùtúnrà rẹ̀,+ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun: ‘Èmi ni ẹni àkọ́kọ́ àti ẹni ìkẹyìn.+ Kò sí Ọlọ́run kankan àfi èmi.+ Àìsáyà 54:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 “Torí pé Aṣẹ̀dá rẹ Atóbilọ́lá+ dà bí ọkọ* rẹ,+Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ni orúkọ rẹ̀,Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì sì ni Olùtúnrà rẹ.+ Ọlọ́run gbogbo ayé la ó máa pè é.+
14 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí, Olùtúnrà yín,+ Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì:+ “Nítorí yín, màá ránṣẹ́ sí Bábílónì, màá sì gé gbogbo ọ̀pá ìdábùú ẹnubodè lulẹ̀,+Àwọn ará Kálídíà sì máa ké jáde nínú ìdààmú, nínú àwọn ọkọ̀ òkun wọn.+
6 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,Ọba Ísírẹ́lì+ àti Olùtúnrà rẹ̀,+ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun: ‘Èmi ni ẹni àkọ́kọ́ àti ẹni ìkẹyìn.+ Kò sí Ọlọ́run kankan àfi èmi.+
5 “Torí pé Aṣẹ̀dá rẹ Atóbilọ́lá+ dà bí ọkọ* rẹ,+Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ni orúkọ rẹ̀,Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì sì ni Olùtúnrà rẹ.+ Ọlọ́run gbogbo ayé la ó máa pè é.+