ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Àwọn Ọba 8:36
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 36 nígbà náà, kí o gbọ́ láti ọ̀run, kí o sì dárí ẹ̀ṣẹ̀ àwọn ìránṣẹ́ rẹ jì wọ́n, ìyẹn àwọn èèyàn rẹ Ísírẹ́lì, nítorí pé wàá tọ́ wọn sí ọ̀nà+ tó yẹ kí wọ́n máa rìn; kí o sì rọ̀jò sórí ilẹ̀ rẹ+ tí o fún àwọn èèyàn rẹ láti jogún.

  • Sáàmù 25:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Ẹni rere àti adúróṣinṣin ni Jèhófà.+

      Ìdí nìyẹn tó fi ń kọ́ àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ ní ọ̀nà tó yẹ kí wọ́n tọ̀.+

  • Àìsáyà 54:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Jèhófà máa kọ́ gbogbo àwọn ọmọ* rẹ,+

      Àlàáfíà àwọn ọmọ* rẹ sì máa pọ̀ gan-an.+

  • Míkà 4:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  2 Ọ̀pọ̀ orílẹ̀-èdè máa lọ, wọ́n á sì sọ pé:

      “Ẹ wá, ẹ jẹ́ ká lọ sórí òkè Jèhófà,

      Sí ilé Ọlọ́run Jékọ́bù.+

      Ó máa kọ́ wa ní àwọn ọ̀nà rẹ̀,

      A ó sì máa rìn ní àwọn ọ̀nà rẹ̀.”

      Torí òfin* máa jáde láti Síónì,

      Ọ̀rọ̀ Jèhófà sì máa jáde láti Jerúsálẹ́mù.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́