Sáàmù 119:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Jèhófà,+ kọ́ mi kí n lè máa tè lé àwọn ìlànà rẹ,Màá sì tẹ̀ lé e délẹ̀délẹ̀.+ Àìsáyà 30:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Bó tiẹ̀ jẹ́ pé Jèhófà máa fi wàhálà ṣe oúnjẹ fún yín, tó sì máa fi ìyà ṣe omi fún yín,+ Olùkọ́ rẹ Atóbilọ́lá ò ní fi ara rẹ̀ pa mọ́ bíi ti tẹ́lẹ̀, o sì máa fi ojú ara rẹ rí Olùkọ́ rẹ Atóbilọ́lá.+ Míkà 4:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ọ̀pọ̀ orílẹ̀-èdè máa lọ, wọ́n á sì sọ pé: “Ẹ wá, ẹ jẹ́ ká lọ sórí òkè Jèhófà,Sí ilé Ọlọ́run Jékọ́bù.+ Ó máa kọ́ wa ní àwọn ọ̀nà rẹ̀,A ó sì máa rìn ní àwọn ọ̀nà rẹ̀.” Torí òfin* máa jáde láti Síónì,Ọ̀rọ̀ Jèhófà sì máa jáde láti Jerúsálẹ́mù.
20 Bó tiẹ̀ jẹ́ pé Jèhófà máa fi wàhálà ṣe oúnjẹ fún yín, tó sì máa fi ìyà ṣe omi fún yín,+ Olùkọ́ rẹ Atóbilọ́lá ò ní fi ara rẹ̀ pa mọ́ bíi ti tẹ́lẹ̀, o sì máa fi ojú ara rẹ rí Olùkọ́ rẹ Atóbilọ́lá.+
2 Ọ̀pọ̀ orílẹ̀-èdè máa lọ, wọ́n á sì sọ pé: “Ẹ wá, ẹ jẹ́ ká lọ sórí òkè Jèhófà,Sí ilé Ọlọ́run Jékọ́bù.+ Ó máa kọ́ wa ní àwọn ọ̀nà rẹ̀,A ó sì máa rìn ní àwọn ọ̀nà rẹ̀.” Torí òfin* máa jáde láti Síónì,Ọ̀rọ̀ Jèhófà sì máa jáde láti Jerúsálẹ́mù.