Àìsáyà 48:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí, Olùtúnrà rẹ, Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì:+ “Èmi, Jèhófà, ni Ọlọ́run rẹ,Ẹni tó ń kọ́ ọ kí o lè ṣe ara rẹ láǹfààní,*+Ẹni tó ń jẹ́ kí o mọ ọ̀nà tó yẹ kí o máa rìn.+ Jòhánù 6:45 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 45 A kọ ọ́ sínú àwọn Wòlíì pé: ‘Jèhófà* máa kọ́ gbogbo wọn.’+ Gbogbo ẹni tó bá ti gbọ́ ti Baba, tó sì ti kẹ́kọ̀ọ́ ń wá sọ́dọ̀ mi. Jémíìsì 1:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Torí náà, tí ẹnikẹ́ni nínú yín ò bá ní ọgbọ́n, kó máa béèrè lọ́wọ́ Ọlọ́run,+ ó sì máa fún un,+ torí ó lawọ́ sí gbogbo èèyàn, kì í sì í pẹ̀gàn*+ tó bá ń fúnni.
17 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí, Olùtúnrà rẹ, Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì:+ “Èmi, Jèhófà, ni Ọlọ́run rẹ,Ẹni tó ń kọ́ ọ kí o lè ṣe ara rẹ láǹfààní,*+Ẹni tó ń jẹ́ kí o mọ ọ̀nà tó yẹ kí o máa rìn.+
45 A kọ ọ́ sínú àwọn Wòlíì pé: ‘Jèhófà* máa kọ́ gbogbo wọn.’+ Gbogbo ẹni tó bá ti gbọ́ ti Baba, tó sì ti kẹ́kọ̀ọ́ ń wá sọ́dọ̀ mi.
5 Torí náà, tí ẹnikẹ́ni nínú yín ò bá ní ọgbọ́n, kó máa béèrè lọ́wọ́ Ọlọ́run,+ ó sì máa fún un,+ torí ó lawọ́ sí gbogbo èèyàn, kì í sì í pẹ̀gàn*+ tó bá ń fúnni.