ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Òwe 2:3-6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 Bákan náà, tí o bá ké pe òye+

      Tí o sì nahùn pe ìfòyemọ̀;+

       4 Tí o bá ń wá a bíi fàdákà,+

      Tí o sì ń wá a kiri bí àwọn ìṣúra tó fara sin;+

       5 Nígbà náà, wàá lóye ìbẹ̀rù Jèhófà,+

      Wàá sì rí ìmọ̀ Ọlọ́run.+

       6 Nítorí Jèhófà fúnra rẹ̀ ló ń fúnni ní ọgbọ́n;+

      Ẹnu rẹ̀ ni ìmọ̀ àti ìfòyemọ̀ ti ń wá.

  • Jòhánù 15:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Tí ẹ bá wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú mi, tí àwọn ọ̀rọ̀ mi sì wà nínú yín, ẹ béèrè ohunkóhun tí ẹ bá fẹ́, ó sì máa rí bẹ́ẹ̀ fún yín.+

  • 1 Jòhánù 5:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Ohun tó dá wa lójú nípa rẹ̀ ni pé,*+ tí a bá béèrè ohunkóhun tó bá ìfẹ́ rẹ̀ mu, ó ń gbọ́ wa.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́