-
Jóòbù 36:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Wò ó! A gbé Ọlọ́run ga nínú agbára rẹ̀;
Olùkọ́ wo ló dà bíi rẹ̀?
-
-
Sáàmù 119:102Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
102 Mi ò yà kúrò nínú àwọn ìdájọ́ rẹ,
Nítorí o ti kọ́ mi.
-