9 Nígbà yẹn, Jésù wá láti Násárẹ́tì ti Gálílì, Jòhánù sì ṣèrìbọmi fún un ní Jọ́dánì.+ 10 Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, bó ṣe ń jáde látinú omi, ó rí i tí ọ̀run ń pínyà, ẹ̀mí sì ń bọ̀ wá sórí rẹ̀ bí àdàbà.+ 11 Ohùn kan sì dún láti ọ̀run pé: “Ìwọ ni Ọmọ mi, àyànfẹ́; mo ti tẹ́wọ́ gbà ọ́.”+