Sáàmù 2:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ẹ jẹ́ kí n kéde àṣẹ Jèhófà;Ó sọ fún mi pé: “Ìwọ ni ọmọ mi;+Òní ni mo di bàbá rẹ.+ Lúùkù 9:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Ohùn kan+ wá dún látinú ìkùukùu náà pé: “Èyí ni Ọmọ mi, ẹni tí mo ti yàn.+ Ẹ fetí sí i.”+