Jẹ́nẹ́sísì 22:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Gbogbo orílẹ̀-èdè tó wà láyé yóò gba ìbùkún fún ara wọn nípasẹ̀ ọmọ*+ rẹ torí pé o fetí sí ohùn+ mi.’” Gálátíà 3:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Èyí jẹ́ nítorí kí ìbùkún Ábúráhámù lè dé ọ̀dọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè nípasẹ̀ Kristi Jésù,+ kí a lè rí ẹ̀mí tí Ọlọ́run ṣèlérí+ gbà nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ wa.
18 Gbogbo orílẹ̀-èdè tó wà láyé yóò gba ìbùkún fún ara wọn nípasẹ̀ ọmọ*+ rẹ torí pé o fetí sí ohùn+ mi.’”
14 Èyí jẹ́ nítorí kí ìbùkún Ábúráhámù lè dé ọ̀dọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè nípasẹ̀ Kristi Jésù,+ kí a lè rí ẹ̀mí tí Ọlọ́run ṣèlérí+ gbà nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ wa.