Jóòbù 21:14, 15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Àmọ́ wọ́n sọ fún Ọlọ́run tòótọ́ pé, ‘Fi wá sílẹ̀! Kò wù wá pé ká mọ àwọn ọ̀nà rẹ.+ 15 Ta ni Olódùmarè, tí a fi máa sìn ín?+ Èrè wo la máa rí tí a bá mọ̀ ọ́n?’+
14 Àmọ́ wọ́n sọ fún Ọlọ́run tòótọ́ pé, ‘Fi wá sílẹ̀! Kò wù wá pé ká mọ àwọn ọ̀nà rẹ.+ 15 Ta ni Olódùmarè, tí a fi máa sìn ín?+ Èrè wo la máa rí tí a bá mọ̀ ọ́n?’+