Jeremáyà 10:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ṣùgbọ́n Jèhófà ni Ọlọ́run lóòótọ́. Òun ni Ọlọ́run alààyè+ àti Ọba ayérayé.+ Nítorí ìbínú rẹ̀, ayé á mì jìgìjìgì,+Kò sì sí orílẹ̀-èdè tó lè fara da ìdálẹ́bi rẹ̀. Náhúmù 1:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ta ló lè dúró nígbà tó bá ń bínú?+ Ta ló sì lè fara da ooru ìbínú rẹ̀?+ Yóò tú ìbínú rẹ̀ jáde bí iná,Àwọn àpáta á sì fọ́ sí wẹ́wẹ́ nítorí rẹ̀.
10 Ṣùgbọ́n Jèhófà ni Ọlọ́run lóòótọ́. Òun ni Ọlọ́run alààyè+ àti Ọba ayérayé.+ Nítorí ìbínú rẹ̀, ayé á mì jìgìjìgì,+Kò sì sí orílẹ̀-èdè tó lè fara da ìdálẹ́bi rẹ̀.
6 Ta ló lè dúró nígbà tó bá ń bínú?+ Ta ló sì lè fara da ooru ìbínú rẹ̀?+ Yóò tú ìbínú rẹ̀ jáde bí iná,Àwọn àpáta á sì fọ́ sí wẹ́wẹ́ nítorí rẹ̀.