Sáàmù 147:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Jèhófà ń gbé àwọn oníwà pẹ̀lẹ́ dìde,+Àmọ́, ó ń rẹ àwọn ẹni burúkú wálẹ̀. Òwe 3:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Ó ń fi àwọn afiniṣẹ̀sín ṣe ẹlẹ́yà,+Àmọ́, ó ń ṣojú rere sí àwọn oníwà pẹ̀lẹ́.+ Sefanáyà 2:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ẹ wá Jèhófà,+ gbogbo ẹ̀yin oníwà pẹ̀lẹ́* ayé,Tó ń pa àṣẹ òdodo* rẹ̀ mọ́. Ẹ wá òdodo, ẹ wá ìwà pẹ̀lẹ́.* Bóyá* ẹ ó rí ààbò ní ọjọ́ ìbínú Jèhófà.+
3 Ẹ wá Jèhófà,+ gbogbo ẹ̀yin oníwà pẹ̀lẹ́* ayé,Tó ń pa àṣẹ òdodo* rẹ̀ mọ́. Ẹ wá òdodo, ẹ wá ìwà pẹ̀lẹ́.* Bóyá* ẹ ó rí ààbò ní ọjọ́ ìbínú Jèhófà.+