Sáàmù 37:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Àmọ́ àwọn oníwà pẹ̀lẹ́ ni yóò jogún ayé,+Inú wọn yóò sì máa dùn jọjọ nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àlàáfíà.+