Sáàmù 72:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ní àkókò rẹ̀, àwọn olódodo yóò gbilẹ̀,*+Àlàáfíà yóò sì gbilẹ̀+ títí òṣùpá kò fi ní sí mọ́. Sáàmù 119:165 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 165 Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àlàáfíà jẹ́ ti àwọn tó nífẹ̀ẹ́ òfin rẹ;+Kò sí ohun tó lè mú wọn kọsẹ̀.* Àìsáyà 48:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ká ní o fetí sí àwọn àṣẹ mi ni!+ Àlàáfíà rẹ ì bá dà bí odò,+Òdodo rẹ ì bá sì dà bí ìgbì òkun.+