Àìsáyà 45:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Torí ohun tí Jèhófà sọ nìyí,Ẹlẹ́dàá ọ̀run,+ Ọlọ́run tòótọ́,Ẹni tó dá ayé, Aṣẹ̀dá rẹ̀ tó fìdí rẹ̀ múlẹ̀ gbọn-in,+Ẹni tí kò kàn dá a lásán,* àmọ́ tó dá a ká lè máa gbé inú rẹ̀:+ “Èmi ni Jèhófà, kò sí ẹlòmíì. Mátíù 5:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 “Aláyọ̀ ni àwọn oníwà tútù,*+ torí wọ́n máa jogún ayé.+ Ìfihàn 21:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ni mo bá gbọ́ ohùn kan tó dún ketekete látorí ìtẹ́ náà, ó sọ pé: “Wò ó! Àgọ́ Ọlọ́run wà pẹ̀lú aráyé, á máa bá wọn gbé, wọ́n á sì jẹ́ èèyàn rẹ̀. Ọlọ́run fúnra rẹ̀ máa wà pẹ̀lú wọn.+
18 Torí ohun tí Jèhófà sọ nìyí,Ẹlẹ́dàá ọ̀run,+ Ọlọ́run tòótọ́,Ẹni tó dá ayé, Aṣẹ̀dá rẹ̀ tó fìdí rẹ̀ múlẹ̀ gbọn-in,+Ẹni tí kò kàn dá a lásán,* àmọ́ tó dá a ká lè máa gbé inú rẹ̀:+ “Èmi ni Jèhófà, kò sí ẹlòmíì.
3 Ni mo bá gbọ́ ohùn kan tó dún ketekete látorí ìtẹ́ náà, ó sọ pé: “Wò ó! Àgọ́ Ọlọ́run wà pẹ̀lú aráyé, á máa bá wọn gbé, wọ́n á sì jẹ́ èèyàn rẹ̀. Ọlọ́run fúnra rẹ̀ máa wà pẹ̀lú wọn.+