ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 1:28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Lẹ́yìn náà, Ọlọ́run súre fún wọn, Ọlọ́run sọ fún wọn pé: “Ẹ máa bímọ, kí ẹ sì pọ̀, kí ẹ kún ayé,+ kí ẹ sì ṣèkáwọ́ rẹ̀,+ kí ẹ máa jọba lórí+ àwọn ẹja inú òkun, àwọn ẹ̀dá tó ń fò lójú ọ̀run àti lórí gbogbo ohun alààyè tó ń rìn lórí ilẹ̀.”

  • Jẹ́nẹ́sísì 9:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Ọlọ́run súre fún Nóà àti àwọn ọmọ rẹ̀, ó sọ fún wọn pé: “Ẹ máa bímọ, kí ẹ pọ̀, kí ẹ sì kún ayé.+

  • Sáàmù 37:29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  29 Àwọn olódodo ni yóò jogún ayé,+

      Wọn yóò sì máa gbé inú rẹ̀ títí láé.+

  • Sáàmù 115:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Ní ti ọ̀run, ti Jèhófà ni,+

      Àmọ́ ayé ni ó fún àwọn ọmọ èèyàn.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́