-
Dáníẹ́lì 3:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Inú wá bí Nebukadinésárì gan-an sí Ṣádírákì, Méṣákì àti Àbẹ́dínígò débi pé ojú rẹ̀ yí pa dà sí wọn,* ó sì pàṣẹ pé kí wọ́n mú kí iná ìléru náà gbóná ní ìlọ́po méje ju ti tẹ́lẹ̀ lọ.
-