Sáàmù 74:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 74 Ọlọ́run, kí ló dé tí o fi kọ̀ wá sílẹ̀ títí láé?+ Kí nìdí tí ìbínú rẹ fi ń jó bí iná* lórí agbo ẹran tó wà ní ibi ìjẹko rẹ?+
74 Ọlọ́run, kí ló dé tí o fi kọ̀ wá sílẹ̀ títí láé?+ Kí nìdí tí ìbínú rẹ fi ń jó bí iná* lórí agbo ẹran tó wà ní ibi ìjẹko rẹ?+