Ẹ́kísódù 15:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Jèhófà, ta ló dà bí rẹ nínú àwọn ọlọ́run?+ Ta ló dà bí rẹ, ìwọ tí o fi hàn pé ẹni mímọ́ jù lọ ni ọ́?+ Ẹni tó yẹ ká máa bẹ̀rù, ká máa fi orin yìn, Ẹni tó ń ṣe ohun ìyanu.+ Sáàmù 89:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun,Ta ló lágbára bí rẹ, ìwọ Jáà?+ Òtítọ́ rẹ yí ọ ká.+
11 Jèhófà, ta ló dà bí rẹ nínú àwọn ọlọ́run?+ Ta ló dà bí rẹ, ìwọ tí o fi hàn pé ẹni mímọ́ jù lọ ni ọ́?+ Ẹni tó yẹ ká máa bẹ̀rù, ká máa fi orin yìn, Ẹni tó ń ṣe ohun ìyanu.+