Òwe 1:5, 6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ọlọ́gbọ́n máa ń fetí sílẹ̀, á sì kọ́ ẹ̀kọ́ sí i;+Olóye máa ń gba ìtọ́sọ́nà ọlọgbọ́n+ 6 Láti lóye òwe àti ọ̀rọ̀ tó díjú,*Ọ̀rọ̀ àwọn ọlọ́gbọ́n àti àlọ́ wọn.+ Mátíù 13:34, 35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Gbogbo nǹkan yìí ni Jésù fi àpèjúwe sọ fún àwọn èrò náà. Ní tòótọ́, kì í bá wọn sọ̀rọ̀ láìlo àpèjúwe,+ 35 kí ohun tí a sọ nípasẹ̀ wòlíì lè ṣẹ, ẹni tó sọ pé: “Màá la ẹnu mi láti sọ àpèjúwe; màá kéde àwọn ohun tó pa mọ́ láti ìbẹ̀rẹ̀.”*+
5 Ọlọ́gbọ́n máa ń fetí sílẹ̀, á sì kọ́ ẹ̀kọ́ sí i;+Olóye máa ń gba ìtọ́sọ́nà ọlọgbọ́n+ 6 Láti lóye òwe àti ọ̀rọ̀ tó díjú,*Ọ̀rọ̀ àwọn ọlọ́gbọ́n àti àlọ́ wọn.+
34 Gbogbo nǹkan yìí ni Jésù fi àpèjúwe sọ fún àwọn èrò náà. Ní tòótọ́, kì í bá wọn sọ̀rọ̀ láìlo àpèjúwe,+ 35 kí ohun tí a sọ nípasẹ̀ wòlíì lè ṣẹ, ẹni tó sọ pé: “Màá la ẹnu mi láti sọ àpèjúwe; màá kéde àwọn ohun tó pa mọ́ láti ìbẹ̀rẹ̀.”*+