Diutarónómì 5:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Ì bá mà dáa o, tí wọ́n bá mú kí ọkàn wọn máa bẹ̀rù mi nígbà gbogbo,+ tí wọ́n ń pa gbogbo àṣẹ mi mọ́,+ nǹkan á máa lọ dáadáa fún àwọn àti àwọn ọmọ wọn títí láé!+
29 Ì bá mà dáa o, tí wọ́n bá mú kí ọkàn wọn máa bẹ̀rù mi nígbà gbogbo,+ tí wọ́n ń pa gbogbo àṣẹ mi mọ́,+ nǹkan á máa lọ dáadáa fún àwọn àti àwọn ọmọ wọn títí láé!+