Òwe 4:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Bàbá mi kọ́ mi, ó sì sọ pé: “Kí àwọn ọ̀rọ̀ mi wà lọ́kàn rẹ digbí.+ Pa àwọn àṣẹ mi mọ́ kí o sì máa wà láàyè.+ Òwe 7:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Pa àwọn àṣẹ mi mọ́ kí o sì wà láàyè;+Pa ẹ̀kọ́* mi mọ́ bí ọmọlójú rẹ. Oníwàásù 12:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Òpin ọ̀rọ̀ náà, lẹ́yìn gbígbọ́ gbogbo rẹ̀ ni pé: Bẹ̀rù Ọlọ́run tòótọ́,+ kí o sì pa àwọn àṣẹ rẹ̀ mọ́,+ nítorí èyí ni gbogbo ojúṣe èèyàn.+ Àìsáyà 48:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ká ní o fetí sí àwọn àṣẹ mi ni!+ Àlàáfíà rẹ ì bá dà bí odò,+Òdodo rẹ ì bá sì dà bí ìgbì òkun.+ 1 Jòhánù 5:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Torí ohun tí ìfẹ́ Ọlọ́run túmọ̀ sí nìyí, pé ká pa àwọn àṣẹ rẹ̀ mọ́;+ síbẹ̀ àwọn àṣẹ rẹ̀ kò nira,+
4 Bàbá mi kọ́ mi, ó sì sọ pé: “Kí àwọn ọ̀rọ̀ mi wà lọ́kàn rẹ digbí.+ Pa àwọn àṣẹ mi mọ́ kí o sì máa wà láàyè.+
13 Òpin ọ̀rọ̀ náà, lẹ́yìn gbígbọ́ gbogbo rẹ̀ ni pé: Bẹ̀rù Ọlọ́run tòótọ́,+ kí o sì pa àwọn àṣẹ rẹ̀ mọ́,+ nítorí èyí ni gbogbo ojúṣe èèyàn.+