Sáàmù 106:21, 22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Wọ́n gbàgbé Ọlọ́run,+ Olùgbàlà wọn,Ẹni tó ṣe àwọn ohun ńlá ní Íjíbítì,+22 Àwọn iṣẹ́ àgbàyanu ní ilẹ̀ Hámù,+Àwọn ohun tó ń bani lẹ́rù ní Òkun Pupa.+
21 Wọ́n gbàgbé Ọlọ́run,+ Olùgbàlà wọn,Ẹni tó ṣe àwọn ohun ńlá ní Íjíbítì,+22 Àwọn iṣẹ́ àgbàyanu ní ilẹ̀ Hámù,+Àwọn ohun tó ń bani lẹ́rù ní Òkun Pupa.+