Sáàmù 72:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Kí ó gbèjà* àwọn tó jẹ́ aláìní,Kí ó gba àwọn ọmọ òtòṣì là,Kí ó sì tẹ àwọn oníjìbìtì rẹ́.+