-
Nọ́ńbà 11:19, 20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Ẹ máa jẹ ẹ́, kì í ṣe ọjọ́ kan tàbí méjì lẹ máa fi jẹ ẹ́, bẹ́ẹ̀ ni kì í ṣe ọjọ́ márùn-ún tàbí mẹ́wàá tàbí ogún (20) ọjọ́ lẹ máa fi jẹ ẹ́, 20 àmọ́ oṣù kan gbáko ni, títí á fi jáde ní ihò imú yín, tó sì máa kó yín nírìíra,+ torí pé ẹ ti kọ Jèhófà, ẹni tó wà ní àárín yín, ẹ sì wá ń sunkún níwájú rẹ̀ pé: “Kí ló dé tí a kúrò ní Íjíbítì?”’”+
-