Nọ́ńbà 14:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Síbẹ̀, kò sí ìkankan nínú àwọn tó fojú rí ògo mi àti àwọn iṣẹ́ àmì+ mi tí mo ṣe ní Íjíbítì àti ní aginjù, tó tún wá ń dán mi wò+ nígbà mẹ́wàá yìí, tí kò sì fetí sí ohùn mi,+ Diutarónómì 6:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 “Ẹ ò gbọ́dọ̀ dán Jèhófà Ọlọ́run yín wò,+ bí ẹ ṣe dán an wò ní Másà.+ Sáàmù 95:8, 9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ẹ má ṣe mú kí ọkàn yín le bí ẹ ṣe ṣe ní Mẹ́ríbà,*+Bíi ti ọjọ́ Másà* ní aginjù,+ 9 Nígbà tí àwọn baba ńlá yín dán mi wò;+Wọ́n pè mí níjà, bó tilẹ̀ jẹ́ pé wọ́n ti rí àwọn iṣẹ́ mi.+
22 Síbẹ̀, kò sí ìkankan nínú àwọn tó fojú rí ògo mi àti àwọn iṣẹ́ àmì+ mi tí mo ṣe ní Íjíbítì àti ní aginjù, tó tún wá ń dán mi wò+ nígbà mẹ́wàá yìí, tí kò sì fetí sí ohùn mi,+
8 Ẹ má ṣe mú kí ọkàn yín le bí ẹ ṣe ṣe ní Mẹ́ríbà,*+Bíi ti ọjọ́ Másà* ní aginjù,+ 9 Nígbà tí àwọn baba ńlá yín dán mi wò;+Wọ́n pè mí níjà, bó tilẹ̀ jẹ́ pé wọ́n ti rí àwọn iṣẹ́ mi.+